![]() |
Taiwo Esther – Yoo Dara |
"Faith plays a major role in our spiritual development. To believe in God, without faith you actually can not believe in God, you have to have" Faith. "In your most holy faith, build yourself up."-Taiwo Esther
Lyrics for the song “Yoo Dara” by Taiwo Esther
Mo gbagbo Beni odami loju,mo gbagbo Beni oye mi yeke yeke,bekun pe dale Kan Ayo mbo lowuro loluwa wi, bekun pe dale Kan Ayo mbo lowuro loso yoo dara.
Biya bajomo fogun odun laye, biya bajomo fo gbon osu laye,isoro gbogbo laye Yi agbara lofun ni,Emi gbagbo o,Beni o dami loju,Emi gbagbo o eni oyemi yeke yeke,papekoto jeun laye Yi koni je baje,ileri oluwa Faye mi awa si imuse yio daa
Ireti mbe o fun igi ti age Lori, ireti mbe o fun igi ti age lule o,boba gbo rirun Omi dedeni aso jade,obediodomu lojo Yan se lodo Loro, Emi gbagbo o Beni odamiloju,Emi gbagbo o eni Oye mi yeke yeke,igbagbo ninu Jesu ki doju ti ni yoo Dara.
Emi gbagbo o dedeni yio dara, ore mi gbekele loluwa ipinle ohun gbogbo ,boba subu loni dedeni wa dide, Ani suru ede lomu ede sere ola Kiri,gbeke le oluwa Ade o lare,gbekele loluwa afun o ni Simi ninu ohun gbogbo
Call:bekun pe dele kan Ayo mbo lowuro loso
Res: yoo dara
Call: botiwu Kori o igi aruwe o
Resp: yoo dare
Call: jebesi lojo yan o bori ogun
Resp: yoo Dara
Call: Agan ma ronu mo wa gbomo jo
Resp:yoo dara
Call: Oba to seti Hannah ko gbagbe re
Resp: yoo dara
Call: sister mi tujuka o jesu lole se
Resp: yoo dara
Call: brother fi gbagbo Jesu lole se
Resp: yoo Dara
Call: Baba yo se ohun rere ti okan re fe
Resp: yoo dara
Call: yeye aye re yio pade de yeye ni
Resp: yoo dara
Call: Ona toluwa pale koseni tole di
Resp: yoo dara
0 Comments