Sing Onto The Lord A New Song; For He Has Done Marvelous Things - Psalm 98:1
ALLELUIA! ALLELUIA! ALLELUIA!
1. The strife is o'er the battle done:
The victory of life is won:
The song of triumph has begun ,
— Alleluia!
2. The pow'rs of death have done their Worst,
But Christ their legions hath Dispersed"
Let shout of holy joy outburst:
—Alleluia!
3. The three sad days have quickly sped
He rises glorious from the dead:
All glory to our risen Head!
— Alleluia !
4. He brake the age-bound chains of hell;
The bars from heav'ns high portals Fell:
Let hymns of praise His triumph tell:
—Alleluia!
5. Lord, by the stripes which wounded Thee
From death's dread sting Thy
Servants free,
That we may live, and sing to Thee
—Alleluia!
Amen.
E Korin Titun Si Oluwa; Nitori O Ti Se Ohun ÃŒyanu - Orin Dafidi 98:1
ALELUYA, ALELUYA, ALELUYA!
1. Ija d'opin, ogun sitan,
Olugbala jagun molu,
Orin ayo lao ma ko; — Aleluya!
2. Gbogbo ipa n'iku ti lo,
Sugbon Kristi f'ogun re ka;
Aye! e ho iho ayo; — Aleluya!
3. Ojo meta na ti koja;
O jinde kuro nin' oku;
E f'ogo fun Oluwa wa —Aleluya!
4. O d'ewon orun apadi,
O silekun orun sile,
E korin iyin 'segun Re — Aleluya!
5. Jesu, nipa iya t'O je
Gba wa lowo oro iku,
K'a le ye, ka si ma yin O - Aleluya
Amin.
0 Comments